The SSS 1 Yoruba scheme of work is a vibrant journey into the rich linguistic and cultural heritage of the Yoruba people.
Through engaging topics that explore the intricacies of the language, traditional customs, and literature, this scheme is designed to deepen your appreciation and fluency in Yoruba.
You get to study grammar, proverbs, and the rich oral traditions that have shaped Yoruba history.
This syllabus is carefully crafted to help you master the language, while also giving you a deeper connection to the cultural values that are integral to Yoruba identity.
SSS 1 YORUBA First Term Scheme of Work
Week 1: Ẹ̀kọ́ ilé (Àṣà Yorùbá)
- Oríkì Ẹ̀kọ́ Ilé
- Ìkíni lórísirísi
- Ìbọ̀wọ̀ fágbà àti Àlejò Ṣíṣe
- Ìwà Ọmọlúàbí
Week 2: Àwọn Ìró Èdè (Èdè)
- Fáwẹ́lì – Àránmúpè àti Àìránmúpè
- Kọ́nsónáǹtì – Àránmúpè àti Àíránmúpè
Week 3: Àwọn Oúnjẹ Ilẹ̀ wa (Àṣà)
- Oríkì Oúnjẹ
- Bí a ṣe n’ṣe Oúnjẹ kọ̀ọ̀kan
- Ìsọ̀rí Oúnjẹ
- Oúnjẹ tí Ìlú/ Agbègbè kan fẹ́ràn
Week 4: Sílébù Èdè Yorùbá (Èdè)
- Oríkì Sílébù
- Ìhun Sílébù (F, KF, N)
- Pípín Ọ̀rọ̀ sí Sílébù
Week 5: Ewì Alohùn (Lítíréṣọ̀)
- Oríkì Ewì Alohùn
- Oríṣìí Ewì Alohùn
- Àdúgbò tí Ọ̀kọ̀ọ̀kan ti wá
Week 6: Iṣẹ́ Abínibí / Ìṣẹ̀nbáyé Yorùbá (Àṣà)
- Oríkì Iṣẹ́ Abínibí àti Àpẹẹrẹ
- Bí a ṣe ń kọ́sẹ́ láyé Àtijọ́
Week 7: Mid-Term break
Week 8: Ìwé kíkà (Lítíréṣọ̀)
- Kíkà Ìwé “Mọ́remí Àjànṣorò – Débọ̀ Awẹ́
- Ìtúpalẹ̀ Ìwé “Mọ́remí Àjànṣorò – Débọ̀ Awẹ́
Week 9: (Èdè)- Ìhun ọ̀rọ̀ àti Ìsẹ̀dá Ọ̀rọ̀
- Ìhun Ọ̀rọ̀ Onísílebù Kan
- Ìhun Ọ̀rọ̀ Ọlọ́pọ̀ Sílébù
- Ìṣẹ̀dá Ọ̀rọ̀- Orúkọ
Week 10: Àṣà Ìgbéyàwó (Àṣà)
- Ìdí tí a fi ń gbéyàwó
- Ìgbéyàwó Ayé Àtijọ́
- Ìgbéyàwó Òde Òní
Week 11: Àtúnyẹ̀wò Ẹ̀kọ́
Week 12: Ìdánwò
Week 13: Ìparí Sáà kì-ín-ní
SSS 1 YORUBA Second Term Scheme of Work
Week 1: Àkàyé àti oríṣiríṣìí àkàyé (ÈDÈ)
- Ọgbọ́n tí a fi ń ṣe àseyege lórí àkàyé
- Kíkà Àyọkà
Week 2: Òwe àti Àkànlò Èdè (ÈDÈ)
- Oríkì òwe àti Àkànlò-Ède
- Oríṣiríṣìí òwe àti Àkànlò-Èdè
- Ìlò òwe àti Àkànlò-Èdè
- Ìyàtọ̀ òwe àti Àkànlò-Èdè
Week 3: Ìwé kíkà (Lítíréṣọ̀)
- Mọ́remí Àjànṣorò – Débọ̀ Awẹ́
- Ìtúpalẹ̀ Ìwé Mọremí Àjànṣorò
Week 4: Àṣà Ìsọmọlórúkọ ní Ilẹ̀ Yorùbá (Àṣà)
- Ìgbàgbọ́ Yorùbá nípa Pàtàkì orúkọ
- Ètò Ìsọmọlórúkọ àti ohun èlò
- Oríṣìí orúkọ Yorùbá àti ìtumọ̀ wọn
Week 5: Aáyan Ògbufọ̀ (Èdè)
- Ìtumọ̀
- Ìtọ́nisọ́nà lórí bí a ṣe ń ṣe aáyan ògbufọ̀
- Títúmọ̀ gbólóhùn kéékèèké láti Èdè gẹ̀ẹ́sì sí Èdè Yorùbá
Week 6: Ìwé kíkà (Lítírésọ̀)
- Mọ́remí Àjànṣorò (Débọ̀ Awẹ́)
Week 7: Mid-Term Break
Week 8: Àṣà oyún níní àti Ìtọ́jú oyún (ÀṢÀ)
- Ìgbàgbọ́ nípa Àgàn, Ọmọbíbí àti Àbíkú
- Ọ̀nà tí à ń gbà dín Àbíkú kù
- Bí a ṣe ń tọ́jú aboyún (abbl)
Week 9: Ìtúpalẹ̀ Àsàyàn Ìwé Onítàn (Lítírésọ̀)
- Ìtúpalẹ̀ Ìwé “Nítorí Owó” – Akínwùnmí Ìsọ̀lá
- Kókó ọ̀rọ̀ inú ìwé
- Ìhunpọ̀ Ìtàn
- Ibùdó Ìtàn
- Ẹ̀dá Ìtan àti Ìfìwàwẹ̀dá
- Ìlò Èdè, Àmúyẹ àti Àléébù
Week 10: Àròkọ (Èdè)
- Ìtumọ̀ àti oríṣìí Àròkọ
- Àròkọ Oníròyìn – Ìtumọ̀
- Ìlànà kíkọ Àròkọ Oníròyìn
- Kí Akẹ́kọ̀ọ́ kọ Àrokọ̀ Oníròyìn kan
Week 11: Àtúnyẹ̀wò Ẹ̀kọ́
Week 12: Ìdánwò
Week 13: Ìparí Sáà kì-ín-ní
SSS 1 YORUBA Third Term Scheme of Work
Week 1: (Èdè) Ìsọ̀rí Ọ̀rọ̀
- Ìtumọ̀ àti Ẹ̀yà Ìsọ̀rí Ọ̀rọ̀
- Ọ̀rọ̀ Orúkọ
- Ọ̀rọ̀- Arọ́pò – Orúkọ
- Ọ̀rọ̀ – Arọ́pò-àfarajorúko
Week 2: (Àṣà) Ìtọ́jú ọmọ
- Pàtàkì Ìtọ́jú Ọmọ dàgbà láti jẹ́ Ọmọ Orílẹ̀-èdè rere
- Ohun tí a fi ń tọ́jú ọmọ
- Bíbá Ọmọ wí lọ́nà tó dára
- Àsìlò Ọmọ
Week 3: Ìtúpalẹ̀ Ewì Àpilẹ̀kọ (Lítírésọ̀)
- Ìtúpalẹ̀ “Ọ̀rọ̀ Ẹnu Akéwì – Ayọ̀mídé Àkànjí
- Kókó Ọ̀rọ̀
- Ìhun Ewì (Ètò)
- Ìlò Èdè, Ìjẹyọ Àṣà
- Àmúyẹ àti Àléébù
Week 4: (Èdè) Àrokọ̀ Ajẹmọ́- Ìsípayá
- Ìtumọ̀ àti Ìlànà kíkọ́ Àrokọ̀ Ajẹmọ́-Ìsípayá
- Èrò Àrokò Ajẹmọ́-Ìsípayá
Week 5: (Àṣà) Àṣà Ìtọ́jú ara
- Ìtumọ̀ àti títọ́jú ara bíi Irun, Èékánná, Eyín, Aṣọ
- Ewu ìlòkulòòogùn
- Ìtọ́jú ara lóde òní
- Orin/Ewì nípa Ìtọ́jú ara
Week 6: (Lítírésọ̀) Ìtúpalẹ̀ Ìwé(Ìtẹ̀síwájú)
- Ìtúpalẹ̀ lórí Ìwé “Ọ̀rọ̀ Ẹnu Akéwì”
- Ayọ̀mídé Àkànjí
Week 7: Mid-Term Break
Week 8: (Èdè) Ìhun gbólóhùn
- Ìtumọ̀ àti Àpólà-Ọ̀rọ̀ orúkọ
- Àpólà-Ọ̀rọ̀ Ìṣe
- Àpólà-Atọ́kùn
Week 9: (Àsà) Oge Ṣíṣe
- Pàtàkì Oge Ṣíṣe
- Oríṣìí ọ̀nà tí à ń gbà ṣe Oge ní Àtijọ́ ara fínfín, Eyín pípa, tìróò lílé, làálì/ osùn kíkùn (Abbl)
- Ìyípadà tó dé Òní- Ètè kíkùn, Irun díndín, Lílu ihò púpọ̀ sí Etí àti imú, bàtà gogoro (abbl)
Week 10: (Àṣà) Ìgbàgbọ́ Yorùbá nípa Olódùmarè/ Àwọn Òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá
- Èrò àti Ìgbàgbọ́ Yorùbá nínú Olódùmarè
- Ẹlẹ́dàá, Asẹ̀dàá, Adákẹ́dạ́jọ́, Alèwílèṣe
- Òrìṣà bí alárinà láàrin Ẹlẹ́dàá àti Ẹ̀dá
- Ìgbàgbọ́ Yorùbá lórí alárinà láàrin Ẹlẹ́dàá àti Ẹ̀dá Jésù àti Mọ̀ọ́mọ́dù
- Àwọn Òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá – Ọbàtálá, Ọ̀rúnmìlà, Ògún, Èṣù, Ṣàngó, Egúngún
Week 11: Àtúnyẹ̀wò Ẹ̀kọ́
Week 12: Ìdánwò
Week 13: Ìparí Sáà kì-ín-ní
SSS 1 YORUBA Recommended Textbook
- Yoruba for Secondary Schools by Ayo Akinwumi
- Complete Yoruba for Senior Secondary Schools by A. O. Abiola and O. A. Ayinla
RECAP
Across the SSS 1 Yoruba scheme, you explore both the language and its cultural significance.
You engage in lessons that brings Yoruba grammar and oral traditions to life, strengthening your command of the language.
Through each topic, you connect linguistic skills with cultural appreciation, immersing yourself in the values and heritage of the Yoruba people.
As a result, your fluency and cultural awareness grows in tandem.
DISCLAIMER: Everything on this page is based on our research of what is obtainable for schools in all the states in the country, including government and some private schools. Schemes of work normally undergo a series of reviews and some schools modify them to suit their specific needs.
While we do all our possible best to keep up with the latest and approved schemes of work in the country, check the specific template your school uses. For example, some private secondary schools integrate the British curriculum. If you teach in such schools, expect to see slight changes to what we offer on this page. If you have any questions or require personalised support, kindly feel free to contact us.